Home » Past Questions » Yoruba » ÌßÊßE Èwo ni ó fi ìgbàgbö Yorùbá nípa ayé lëyìn ikú hàn nínú ...

ÌßÊßE Èwo ni ó fi ìgbàgbö Yorùbá nípa ayé lëyìn ikú hàn nínú ...


Question

ÌßÊßE
Èwo ni ó fi ìgbàgbö Yorùbá nípa ayé lëyìn ikú hàn nínú ìwònyí?

Options

A) Ôdún egúngún

B) Ôdún ògún

C) Ìÿípà ôdç

D) Ààrò kíkó

The correct answer is A.

Explanation:

Yorùbá gbàgbö pé àwôn êdá tí wön ti kú tí wön tõrun wá sí ayé ni egúngún.

More Past Questions:


Dicussion (1)