Home » Past Questions » Yoruba » LÍTÍRÉßÕ Ìwé Ìyán Ogún Ôdún ni ìbéèrè dá lé. Çni tó kó gbog...

LÍTÍRÉßÕ Ìwé Ìyán Ogún Ôdún ni ìbéèrè dá lé. Çni tó kó gbog...


Question

LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ìyán Ogún Ôdún ni ìbéèrè dá lé.
Çni tó kó gbogbo ômô-ogun jô tó sì ÿètò ìjagun ni

Options

A) Balógun

B) Ògúnlérè

C) Agbégéþdé

D) Arówóná

The correct answer is A.

Explanation:

Nítorí oyé tó jç láàrìn ìlú.

More Past Questions:


Dicussion (1)