Home » Past Questions » Yoruba » Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó t...

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó t...


Question

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.


Ilé-ayé ò jë nýkan,

Àlá lásán ni,

Ôkàn tó þ sùn ti dòkú,

Nýkan ò rí bí a ti rò ó

Ilé-ayé gbçgë. 5

Sàréè ì ÿopin êdá.

Eérú fún eérú,

Eruku fún eruku,

Lôba-òkè sô fénìyàn,

Tó j’Ôlörun nípè. 10

Àmö hùwà bí çni pé,

Ojoojúmö lêdá þ súnmölé.

Máà gbëkêké ôlá

Máà nígbçkêlé nínú ôrõ.

Alágbára ayé, ç rôra ÿe. 15

Bí ó ti wù ká ki lökàn tó,

Kìkì ní í lù,

Báa bá gbölù ikú,

Àtorin arò ti þ kôjá lóde.

Ojú ogun layé. 20

Má bojú wêyìn,

Jà bí akin lójú ìjà.

Rántí ayé àkôni tó kôjá,

Wo àwòköÿe wôn fún ôjö õla tìrç.

Gbé ìgbé-ayé alààyè, 25

Jë kí òkú sunkún ara wôn.

Àwé, má ronú mö,

Jë ká máa ÿiÿé lô.

Máa jagun lô,

Má wêyìn, 30

Má ÿiyè méjì,

Bó pë, bó yá,

Ayõ þ bõ.


Àwé túmõ sí

Options

A)
ikú
B)
ayé
C)
õrë
D)
ôlörõ

The correct answer is C.

Explanation:

Orúkõ míràn fún õrë nílê Yorùbá ni àwé.

More Past Questions:


Dicussion (1)