Home » Past Questions » Yoruba » Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó t...

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó t...


Question

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.


Babárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge, çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé, inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.

Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya. Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé ôkô.

Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà. Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.

Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí, ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn, wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.


Àwôn òbí Fôláÿadé kábàámõ ìwà wôn nítorí pé

Options

A)
ibi ti wön fojú sí, ònà ò gbabê lô
B)
nýkan ò dánmörán fún wôn mö
C)
Babárìndé ti gbéyàwó, ó sì ti bímô
D)
oògùn ti wön ÿe kò ÿiÿë mö.

The correct answer is A.

Explanation:

Babárìndé tí wön ròpin di ènìyàn pàtàkì ÿùgbön Atáyéwá di òtòÿì.

More Past Questions:


Dicussion (1)