Home » Past Questions » Yoruba » ÈDÈ Éwo ló bá ìlànà àkôtö òde-òní mu?

ÈDÈ Éwo ló bá ìlànà àkôtö òde-òní mu?


Question

ÈDÈ
Éwo ló bá ìlànà àkôtö òde-òní mu?

Options

A) Ìbà jë ômô ènìyàn kò dá iÿë Olúwa dúró

B) Ìbáàjë ômô ènìyàn kò dá iÿë Olúwa dúró

C) Ìbàjë ômô ènìyàn kò dá iÿë Olúwa dúró

D) Ìbàjë ômô ènìyàn kòdá iÿë Olúwa dúró

The correct answer is C.

Explanation:

Gbólóhùn yíì ló bá ìlànà àkôtö òde-òní mu dáadáa.

More Past Questions:


Dicussion (1)