Home » Past Questions » Yoruba

Yoruba Past Questions | JAMB, WAEC, NECO and Post UTME Past Questions

Yoruba is a language spoken in Nigeria and West Africa at large. The main language of people of the Oyo Empire and Benin Empire. The number of speakers of the Yoruba language is approaching 30 million.

Study the following Yoruba past questions and answers for JAMB. Prepare yourself with official past questions and answers for your upcoming examinations.

Select Exam Body:

Select Exam Year:

Select Page:

Study Mode:Question 1

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.

Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.

Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.

Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.

Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.

Kí ni ó fún Ôba Fadérera lólìkí?

Options

A)
Ìwà rere rê
B)
Oko iÿu rê
C)
Çwà rê
D)
Irè oko rê
Comments (2)

Question 2

Êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla ni

Options

A) àìsí òjò

B) ìkòokò tí þ dààmú ìlú

C) àìsí omi

D) iÿë õfë ÿíÿe lóko ôba

Comments (1)

Question 3

Asõtàn fi Ôba Fadérera hàn bíi

Options

A) apànìyàn

B) onínú rere

C) aláìbìkítà

D) aláìláàánú

Comments (1)

Question 4

Ohun ti ó mú irè oko ôba tà ju ti ará ìlú lô ni pé

Options

A) ôba gbön jù wön lô

B) irè oko ôba kò wön

C) iÿu oko ôba tóbi ju ti ará ìlú

D) ôba ní agbára

Comments (1)

Question 5

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.

Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.

Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.

Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.

Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.

Ìtumõ ráúráú nínú àyôkà yìí ni

Options

A) tipátipá

B) kíakía

C) pátápátá

D) tôlàtôlà

Comments (1)

Question 6

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

Orí loníÿe, êdá làyànmö.

Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.

A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;

Orí níí ÿatökùn fúnni.

Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,

Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,

Orí ló lôjö gbogbo.

Orí çni làwúre çni;

Orí ló yç kénìyàn ó sìn.

Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,

Àyànmö ni.

Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,

ßebí orí ló sohun gbogbo.

Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,

Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.

Ç má fõrõ àyànmö wéra.

Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,

Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.

Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.

Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.

Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.

Táyé bá ÿelá tílá fi kó,

Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê

Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo

Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni

Kò sëni pa Lágbájá,

Kò sëni pa Làkáÿègbè;

Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.

Orí jà ó joògùn

Orí là bá máa bô löjö gbogbo

Orí ni ààbò çni,

Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.

Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.

Máà bënìkan sô,

Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.

Kókó inú ewì yìí ni pé

Options

A)
Orí tó ti bàjë kò ÿeé túnÿe
B)
ohun orí ëní yàn ní í yôni lënu
C)
àyànmö kò gbóògùn
D)
àdáyébá nìpín çni
Comments (1)

Question 7

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

Orí loníÿe, êdá làyànmö.

Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.

A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;

Orí níí ÿatökùn fúnni.

Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,

Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,

Orí ló lôjö gbogbo.

Orí çni làwúre çni;

Orí ló yç kénìyàn ó sìn.

Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,

Àyànmö ni.

Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,

ßebí orí ló sohun gbogbo.

Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,

Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.

Ç má fõrõ àyànmö wéra.

Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,

Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.

Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.

Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.

Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.

Táyé bá ÿelá tílá fi kó,

Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê

Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo

Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni

Kò sëni pa Lágbájá,

Kò sëni pa Làkáÿègbè;

Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.

Orí jà ó joògùn

Orí là bá máa bô löjö gbogbo

Orí ni ààbò çni,

Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.

Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.

Máà bënìkan sô,

Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.

Ìtumõ kádàrá nínú ewì yìí ni

Options

A)
ìpín
B)
ìwá
C)
ìgbésí-ayé
D)
ilé-ayé
Comments (1)

Question 8

Ìdí ti akéwì fi ní ká bórí sô ká máà bënìkan sô ni pé

Options

A)
ènìyàn kò fëni förõ
B)
a kò mçni tó fëni dénú
C)
çnìkan kò báni yan orí çni
D)
orí ni êdá sìn wáyé
Comments (1)

Question 9

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

Orí loníÿe, êdá làyànmö.

Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.

A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;

Orí níí ÿatökùn fúnni.

Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,

Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,

Orí ló lôjö gbogbo.

Orí çni làwúre çni;

Orí ló yç kénìyàn ó sìn.

Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,

Àyànmö ni.

Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,

ßebí orí ló sohun gbogbo.

Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,

Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.

Ç má fõrõ àyànmö wéra.

Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,

Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.

Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.

Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.

Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.

Táyé bá ÿelá tílá fi kó,

Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê

Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo

Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni

Kò sëni pa Lágbájá,

Kò sëni pa Làkáÿègbè;

Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.

Orí jà ó joògùn

Orí là bá máa bô löjö gbogbo

Orí ni ààbò çni,

Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.

Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.

Máà bënìkan sô,

Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.

Nínú ìlà 14-15, ohun ti akéwì sô nípa Táyé àti Këhìndé ni pé

Options

A)
ômô ìyá kan niwön
B)
orí õkan sunwõn ju èkejì lô
C)
àkôölê oníkálùkù, õtõõtõ ni
D)
Táyé kò lè ran Këhìndé löwö
Comments (1)

Question 10

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

Orí loníÿe, êdá làyànmö.

Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.

A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;

Orí níí ÿatökùn fúnni.

Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,

Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,

Orí ló lôjö gbogbo.

Orí çni làwúre çni;

Orí ló yç kénìyàn ó sìn.

Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,

Àyànmö ni.

Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,

ßebí orí ló sohun gbogbo.

Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,

Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.

Ç má fõrõ àyànmö wéra.

Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,

Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.

Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.

Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.

Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.

Táyé bá ÿelá tílá fi kó,

Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê

Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo

Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni

Kò sëni pa Lágbájá,

Kò sëni pa Làkáÿègbè;

Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.

Orí jà ó joògùn

Orí là bá máa bô löjö gbogbo

Orí ni ààbò çni,

Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.

Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.

Máà bënìkan sô,

Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.

A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa túmõ sí pé

Options

A) êdá þ fi wàdùwàdù ÿe nýkan

B) êdá þ lépa ohun ti kò yàn látõrun

C) ojú êdá kò gbébìkan

D) ìÿòro êdá àmútõrun wá ni

Comments (1)